Ìbùkún ni fún ọ, Ísírẹ́lì,ta ni ó dà bí ì rẹ,ẹni tí a gbàlà láti ọ̀dọ̀ Olúwa?Òun ni àṣà àti ìrànwọ́ rẹ̀àti idà ọlá ńlá rẹ̀.Àwọn ọ̀ta rẹ yóò tẹríba fún ọ,ìwọ yóò sì tẹ ibi gíga wọn mọ́lẹ̀.”