Deutarónómì 33:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítòótọ́, ó fẹ́ràn àwọn ènìyàn an rẹ̀,gbogbo àwọn ènìyàn mímọ́ wà ní ọwọ́ rẹ̀.Ní ẹṣẹ̀ rẹ̀ ni wọ́n ti foríbalẹ̀,àti lọ́dọ̀ rẹ̀ ni wọ́n ti ń gba ọ̀rọ̀,

Deutarónómì 33

Deutarónómì 33:2-4