Deutarónómì 33:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)
Ó sì wí pé:“Olúwa ti Sínáì wá,ó sì yọ sí wọn láti Ṣéírì wáó sì tàn án jáde láti òkè Páránì wá.Ó ti ọ̀dọ̀ ẹgbẹgbàarùn ún àwọn mímọ́ wáláti ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ ni òfin kan amúbíiná ti jáde fún wọn wá.