Deutarónómì 33:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ti Jóṣẹ́fù ó wí pé:“Kí Olúwa bùkún ilẹ̀ rẹ,fún ohun iyebíye láti ọ̀run pẹ̀lú ìrìàti ibú tí ó ń bẹ níṣàlẹ̀;

Deutarónómì 33

Deutarónómì 33:8-20