Deutarónómì 33:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ti Bẹ́ńjámínì ó wí pé:“Jẹ́ kí olùfẹ́ Olúwa máa gbé ní àlàáfíà lọ́dọ̀ rẹ̀,òun a máa bò ó ní gbogbo ọjọ́,ẹni tí Olúwa fẹ́ràn yóò máa sinmi láàrin èjìká rẹ̀.”

Deutarónómì 33

Deutarónómì 33:10-20