Deutarónómì 32:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí idì ti íru ìtẹ́ rẹ̀ ti ó sì ńrábàbà sórí ọmọ rẹ̀,tí ó na ìyẹ́ apá rẹ̀ láti gbé wọn ki ó sìgbé wọn sórí ìyẹ́ apá rẹ̀.

Deutarónómì 32

Deutarónómì 32:4-14