Deutarónómì 32:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ihà ni ó ti rí i,ní ihà níbi tí ẹranko kò sí.Ó yíká, ó sì tọ́jú u rẹ̀,ó pa á mọ́ bí ẹyin ojú u rẹ̀.

Deutarónómì 32

Deutarónómì 32:8-20