Deutarónómì 31:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí mo mọ irú ọlọ̀tẹ̀ àti ọlọ́rùn líle tí ẹ jẹ́. Bí o bá ṣe ọlọ̀tẹ̀ sí Olúwa nígbà tí mo pàpà wà láyé Pẹ̀lú u yín, báwo ní ẹ ó ti ṣe ọlọ̀tẹ̀ tó nígbà tí mo bá kú tan!

Deutarónómì 31

Deutarónómì 31:18-30