Deutarónómì 31:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Gba ìwé òfin yìí kí o sì fi sí ẹ̀gbẹ́ àpótí i májẹ̀mú Olúwa Ọlọ́run rẹ. Níbẹ̀ ni yóò wà bí ẹ̀rí sí ọ.

Deutarónómì 31

Deutarónómì 31:21-30