Deutarónómì 31:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Mo jẹ́ ọmọ ọgọ́fà ọdún báyìí àti pé èmi kò ni lè darí i yín mọ́. Olúwa ti sọ fún mi pé, ‘O kò ní kọjá Jọ́dánì.’

Deutarónómì 31

Deutarónómì 31:1-4