Deutarónómì 31:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Móṣè jáde tí ó sì sọ àwọn ọ̀rọ̀ wọ̀nyí sí gbogbo Ísírẹ́lì pé:

Deutarónómì 31

Deutarónómì 31:1-7