Deutarónómì 27:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ègún ni fún ọkùnrin náà tí ó gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀ láti pa ènìyàn láìjẹ̀bi.”Nígbà náà ni gbogbo ènìyàn wọ̀nyí yóò wí pé, “Àmín!”

Deutarónómì 27

Deutarónómì 27:17-26