Deutarónómì 27:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ègún ni fún ọkùnrin náà tí ó ní ìbalòpọ̀ pẹ̀lú ẹranko.”Nígbà náà ni gbogbo ènìyàn wọ̀nyí yóò wí pé, “Àmín!”

Deutarónómì 27

Deutarónómì 27:12-26