Deutarónómì 27:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbọ́ràn sí Olúwa Ọlọ́run rẹ kí o sì tẹ̀lé àṣẹ àti òfin rẹ̀ tí mo ń fi fún ọ lónìí.”

Deutarónómì 27

Deutarónómì 27:1-19