Deutarónómì 24:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Rántí ohun tí Olúwa Ọlọ́run rẹ ṣe sí Míríámù lójú ọ̀nà lẹ́yìn ìgbà tí o jáde kúrò ní Éjíbítì.

Deutarónómì 24

Deutarónómì 24:5-19