Deutarónómì 24:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ti àrùn ẹ̀tẹ̀ kíyèsára láti máa ṣe gẹ́gẹ́ bí àwọn àlùfáà tí wọ́n jẹ́ ọmọ Léfì ti pàṣẹ fún ọ. O ní láti máa fi ìṣọ́ra tẹ̀lé ohun tí mo ti pa láṣẹ fún wọn.

Deutarónómì 24

Deutarónómì 24:4-14