Deutarónómì 23:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí o bá jẹ́jẹ̀ẹ́ fún Olúwa Ọlọ́run rẹ, má ṣe lọ́ra láti san án, nítorí Olúwa Ọlọ́run rẹ yóò béèrè rẹ̀ lọ́wọ́ ọ rẹ, o sì máa jẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀.

Deutarónómì 23

Deutarónómì 23:20-25