Deutarónómì 20:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pa wọ́n run pátapáta, àwọn ọmọ Hítì, ọmọ Ámórì, ọmọ Kénánì, ọmọ Pérísì, ọmọ Hífì, ọmọ Jébúsì gẹ́gẹ́ bí Olúwa Ọlọ́run rẹ ti pa á láṣẹ fún ọ.

Deutarónómì 20

Deutarónómì 20:14-20