Ṣùgbọ́n, nínú àwọn ìlú ti àwọn orílẹ̀ èdè tí Olúwa Ọlọ́run rẹ ń fún ọ gẹ́gẹ́ bí ogún, má ṣe dá ohun ẹlẹ́mìí kankan sí.