Deutarónómì 15:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ lè béèrè ìsanpadà lọ́dọ̀ àjòjì. Ṣùgbọ́n ẹ fagi lé gbéṣè yóòwù kó jẹ́ tí arákùnrin yín jẹ yín.

Deutarónómì 15

Deutarónómì 15:1-8