Deutarónómì 1:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo wí fún-un yín nígbà náà pé, “Èmi nìkan kò lè dá ẹrù u yín gbé mọ́.

Deutarónómì 1

Deutarónómì 1:3-14