Deutarónómì 1:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa Ọlọ́run yín ti sọ yín di púpọ̀ lónìí, ẹ̀yin sì ti pọ̀ bí ìràwọ̀ ní ojú ọ̀run.

Deutarónómì 1

Deutarónómì 1:3-14