Deutarónómì 1:45 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ padà, ẹ sì sunkún níwájú Olúwa, òun kò sì fetí sí igbe ẹkún yín, Ó sì kọ etí dídi sí i yín.

Deutarónómì 1

Deutarónómì 1:43-46