Dáníẹ́lì 4:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Nebukadinésárì ọba,Sí gbogbo ènìyàn, orílẹ̀ àti onírúurú èdè, tí ó ń gbé ní àgbáyé:Kí Àlàáfíà máa pọ̀ síi fún un yín.Kí ẹ ṣe rere tó pọ̀!

2. Ó jẹ́ ìdùnnú fún mi láti fi iṣẹ́ àmì àti ìyanu tí Ọlọ́run Ọ̀gá Ògo ti ṣe fún mi hàn.

Dáníẹ́lì 4