Dáníẹ́lì 5:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Beliṣáṣárì, ọba ṣe àsè ńlá fún ẹgbẹ̀rún (1,000) kan nínú àwọn ọlọ́lá a rẹ̀, ó sì mu wáìnì pẹ̀lú u wọn.

Dáníẹ́lì 5

Dáníẹ́lì 5:1-3