Dáníẹ́lì 11:43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò gba àkóso ìṣúra wúrà àti fàdákà àti gbogbo orò Éjíbítì, pẹ̀lú ti Líbíyà àti Núbíà nígbà tí ó mú wọn tẹríba.

Dáníẹ́lì 11

Dáníẹ́lì 11:38-45