Dáníẹ́lì 10:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sọ pé, “Dáníẹ́lì ẹni tí a yànfẹ́ gidigidi gba ọ̀rọ̀ tí mo fẹ́ bá ọ sọ yìí yẹ̀wò dáadáa, kí o sì dìde, nítorí tí a rán mi sí ọ.” Bí ó ṣe sọ èyí fún mi, mo dìde ní ìwárìrì.

Dáníẹ́lì 10

Dáníẹ́lì 10:9-13