Àwọn Hébérù 3:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè nítòótọ́ sì ṣe olóòótọ́ nínú gbogbo iṣẹ́ rẹ̀ nínú ilé Ọlọ́run, bí ìránṣẹ́, fún ẹ̀rí ohun tí a ó sọ̀rọ̀ wọ̀n ní ìgbà ìkẹyìn.

Àwọn Hébérù 3

Àwọn Hébérù 3:1-6