Àwọn Hébérù 3:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ọwọ́ ènìyàn kan ni a sá à ti kọ́ olúkúlùkù ilé; ṣùgbọ́n ẹni tí ó kọ́ ohun gbogbo ni Ọlọ́run.

Àwọn Hébérù 3

Àwọn Hébérù 3:2-14