Àwọn Hébérù 11:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn obìnrin ri òkú wọn gbà nípa àjíǹde: a sì da àwọn ẹlòmíràn lóró, wọ́n kọ̀ láti gba ìdásílẹ̀; kí wọn ba lè rí àjíǹde tí o dára jù gbà;

Àwọn Hébérù 11

Àwọn Hébérù 11:31-40