Àwọn Hébérù 11:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí wọn pa agbára iná, ti wọn bọ́ lọ́wọ́ ojú idà, tí a sọ di alágbára nínú àìlera, ti wọn dí akọni ni ìjà, wọn lé ogun àwọn àjèjì sá.

Àwọn Hébérù 11

Àwọn Hébérù 11:27-36