Àwọn Hébérù 1:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti nípa ti àwọn ańgẹ́lì, ó wí pé;“Ẹni tí ó dá àwọn ańgẹ́lì rẹ̀ ní ẹ̀mi,àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ ní ọwọ́ ìná.”

Àwọn Hébérù 1

Àwọn Hébérù 1:6-12