Àwọn Hébérù 1:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kì í ha á ṣe ẹ̀mí tí ń jísẹ́ ni àwọn ańgẹ́lì í ṣe bí; tí a rán lọ síta láti máa sisẹ́ fún àwọn tí yóò jogún ìgbàlà?

Àwọn Hébérù 1

Àwọn Hébérù 1:13-14