Àwọn Hébérù 1:13-14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

13. Èwo nínú àwọn ańgẹ́lì ní a gbọ́ pé Ọlọ́run fi ìgbà kan wí fún pé,“Jókòó ní ọwọ́ ọ̀tún mitítí èmi yóò fi sọ àwọn ọ̀ta rẹdi àpótí ìtìsẹ̀ rẹ”?

14. Kì í ha á ṣe ẹ̀mí tí ń jísẹ́ ni àwọn ańgẹ́lì í ṣe bí; tí a rán lọ síta láti máa sisẹ́ fún àwọn tí yóò jogún ìgbàlà?

Àwọn Hébérù 1