“Dájúdájú, ojú Olúwa Ọlọ́run ń bẹ̀lára ilẹ̀ ọba tó kún fún ẹ̀ṣẹ̀.Èmi yóò pa á run kúrò lórí ilẹ̀Ṣíbẹ̀ Èmi kò ni pa ilé Jákọ́bù run pátapáta,”ni Olúwa wí.