Ámósì 9:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)
“Ọjọ́ náà ń bọ,” ni Olúwa wí,“Tí ẹni tí ń tulẹ̀ yóò lé ẹni tí ń kórè báTí ẹni tí ń fún èso àjàrà yóò lé ẹni tí ń gbìn báÀwọn òkè ńlá yóò sì kán ọtí wáìnì sílẹ̀Tí yóò sì ṣàn láti ara àwọn òkè kékèké.