Ámósì 1:13-15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

13. Èyí ni ohun tí Olúwa wí:“Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ mẹ́ta ti Ámónìàní mẹ́rin, Èmi kò ní yí ìpinnu ìjìyà mi padà,Nítorí wọn ti la inú àwọn aboyún Gílíádìkí wọ́n ba à lè fẹ ilẹ̀ wọn sẹ́yìn.

14. Èmi yóò rán iná sí ara odi RábàÈyí tí yóò jó àwọn ààfin rẹ̀ runpẹ̀lú igbe ní ọjọ́ ogunpẹ̀lú ìjì ní ọjọ́ ààjà

15. Ọba wọn yóò sì lọ sí ìgbèkùnÒun àti àwọn ọmọ aládé rẹ̀ lápapọ̀,”ni Olúwa wí.

Ámósì 1