Ámósì 1:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni ohun tí Olúwa wí:“Nítorí ẹ̀ṣẹ̀ mẹ́ta ti Ámónìàní mẹ́rin, Èmi kò ní yí ìpinnu ìjìyà mi padà,Nítorí wọn ti la inú àwọn aboyún Gílíádìkí wọ́n ba à lè fẹ ilẹ̀ wọn sẹ́yìn.

Ámósì 1

Ámósì 1:7-15