Àìsáyà 64:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ a máa wá fún ìrànlọ́wọ́ àwọn tí wọnń fi ayọ̀ ṣe ohun tótọ́,tí ó rántí ọ̀nà rẹ.Ṣùgbọ́n nígbà tí a bẹ̀rẹ̀ sí dẹ́ṣẹ̀ sí wọn,inú bí ọ.Báwo ni a ó ṣe gbà wá là?

Àìsáyà 64

Àìsáyà 64:1-11