Àìsáyà 64:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti ìgbà ìwásẹ̀ kò sí ẹni tí ó gbọ́ ríkò sí etí kan tí ó gbọ́ ọ,kò sí ojú tí ó tí ì rí Ọlọ́run mìíràn lẹ́yìn rẹ,tí ó máa ń ṣe nǹkan lórúkọ àwọn tí ó dúró dè é.

Àìsáyà 64

Àìsáyà 64:1-10