Àìsáyà 62:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A ó sì pè wọ́n ní Ènìyàn Mímọ́,ẹni ìràpadà Olúwa;a ó sì máa pè ọ́ ní ìwákiri,Ìlú tí a kì yóò kọ̀ sílẹ̀.

Àìsáyà 62

Àìsáyà 62:10-12