Àìsáyà 59:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òwú wọn kò wúlò fún aṣọ rírán;wọn kò lè fi aṣọ tí wọ́n hun bo ara wọn.Iṣẹ́ wọn jẹ́ ti ibi, ìwà jàǹdàkú sì kún ọwọ́ wọn.

Àìsáyà 59

Àìsáyà 59:5-7