Àìsáyà 51:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òdodo mi ń bọ̀ wá kíkankíkan,ìgbàlà mi ń bọ̀ lójú ọ̀nà,àti apá mi yóò sì mú ìdájọ́ wásí àwọn orílẹ̀ èdè.Àwọn erékùṣù yóò wò míwọn yóò sì dúró ní ìrètí fún apá mi.

Àìsáyà 51

Àìsáyà 51:1-10