Àìsáyà 51:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Tẹ́tí sími, ẹ̀yin ènìyàn mi;gbọ́ tèmi, ẹ̀yin orílẹ̀ èdè mi:Òfin yóò ti ọ̀dọ̀ mi jáde wá;ìdájọ́ mi yóò di ìmọ́lẹ̀ sí àwọn orílẹ̀ èdè.

Àìsáyà 51

Àìsáyà 51:1-10