Àìsáyà 51:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ẹ wo Ábúráhámù baba yín,àti Ṣérà, ẹni tó bí i yín.Nígbà tí mo pè é, òun nìkan ni,Èmi sì bùkún un, mo sì sọ́ọ́ di ọ̀pọ̀lọpọ̀.

Àìsáyà 51

Àìsáyà 51:1-12