Àìsáyà 51:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Tẹ́tí sí mi, ẹ̀yin tí ó ń lépa òdodoàti ẹ̀yin tí ń wá Olúwa:Wo àpáta, nínú èyí tí a ti gé yín jádeàti ihò òkúta níbi tí a ti gbẹ́ yín jáde;

Àìsáyà 51

Àìsáyà 51:1-5