Àìsáyà 50:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa àwọn ọmọ-ogun ni ó ń ràn mí lọ́wọ́.Ta ni ẹni náà tí yóò dámí lẹ́bi?Gbogbo wọn yóò gbó bí aṣọ;kòkòrò ni yóò sì mú wọn jẹ.

Àìsáyà 50

Àìsáyà 50:1-11