Àìsáyà 50:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni tí ó dámiláre wà nítòsí.Ta ni ẹni náà tí yóò fẹ̀ṣùn kàn mí?Jẹ́ kí a kojú ara wa!Ta ni olùfisùn mi?Jẹ́ kí ó kòmí lójú!

Àìsáyà 50

Àìsáyà 50:1-11