Àìsáyà 46:8-10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

8. “Rántí èyí, fi í sí ọkàn rẹ,fi sí ọkàn rẹ, ẹ̀yin ọlọ̀tẹ̀.

9. Rántí àwọn nǹkan àtẹ̀yìnwá, àwọn ti àtijọ́tijọ́;Èmi ni Ọlọ́run, kò sì sí ẹlọ̀mìíràn;Èmi ni Ọlọ́run, kò sí ẹlòmìíràn bí ì mi.

10. Mo fi òpin hàn láti ìbẹ̀rẹ̀ wá,láti àtètèkọ́ṣe, ohun tí ó sì ń bọ̀ wá.Mo wí pé: Ète mi yóò dúró,àti pé èmi yóò ṣe ohun tí ó wù mí.

Àìsáyà 46