Àìsáyà 44:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn kò mọ nǹkankan, nǹkankan kò yé wọn;a fi ìbòjú bo ojú wọn, wọn kò lè rí nǹkankan;bẹ́ẹ̀ ni àyà wọn sébọ́, wọn kò lè mọ nǹkankan.

Àìsáyà 44

Àìsáyà 44:9-21